8a1954466988805fef28d8615ed1.jpg]()
Oro Akoso
Iwa-eda Adamu je Ma atiio eda. O tun tokasi ohun gbogbo ninu wa ti oje oiooto si iwa igbe aye anikanjopon wa. Lona ti omoiuabi, a tumo iwa-eda yi si iwa ese ti eniyanjogun lati odo obi re akoko. (Samuel 51:5).
Ni ibere pepe, nigba ti Adamu ati Efa wa ni Ogba Edeni, won ni iwa ti Oiorun (iwa mimo: Lev. 11: 45, 153m. 2:2) sugbon bi won ti ntesiwaju, Satani wa, 0 tan won je iati se aigboran si ase Olorun. Nitori ife won lati di ominira, won so ibasepo won peiu Olorun, eni ti i se orisun iye gbogbo, won si subu kuro ninu oore-ofe Oiorun. Eda Olorun fI eniyan siie, eda ese si gba akoso. (Gen. 3: 1-9, 23, 24). Fun idi eyi, Satani ni orisun eda Adamu yii. O je eletan oludanwo to maa nje ki eniyan o se awawi Lori ese to nda.
Gege bi Bibeli ti so, ese ni riru ofin. (lJohn 3:4). Oiukuiuku ese ni o je isote si ododo, nitorina, awon elese je alaisododo. Bi 0 se wu ki 0 ga to, ti 0 ba ru oiin Oiorun ni onakona, elese ni o.
Ki eniyan to la bo iowo eda Adamu yii, oun ni lati, dipo ki o maa gbiyanju iati bori ese nipa ife tabi agbara ara re, ki o gba ipese Olorun fun ipese Olorun fun isegun Iori ese: Emi Mimo, eni ti ngbe ninu re, ti 0 sin fun un ni agbara.
Afiyesi
(1) Iru ese ngbe inu re nitori pe ninu ese ni a bio(Psalm51:5).
(2) Eyi to tun buruju ni pe, o 0 ie e dekun ese nidida iaye ara a re.
(3) iroyin ayo nip e, Olorun ti seto ninu Jesu Kristi lati ja ajaga ese kuro ninu
aye re. (Romans 5:8). Nitori naa, dekun ati maa danikan ba eseja ijakadi, jewo awon ese re ti o mo fun un. (Rom. 10:9-10; Prov. 28:13).
(4) Lati bori eda Adamu ; sa fun gbogbo ifarahan (1Tim. 6:11), maa se deede ninu irin re pelu Jesu, ati ki o si maa gbe ninu Re ni igba gbogbo (John 15. 4). Nigba ti 0 ba se gbOgbo nnkan wonyii, a o paaro eda Adamu re pelu eda Olorun, wa a ni iriri okan titun lati maa se ohun to to.