Mo tún ti dé pẹ̀lú ohùn ẹnu mi, ọmọ Yorùbá ponbele.
AṢA IMURA NÍ ILẸ YORÙBÁ ni Ohun ti mo muwa fun yin loni. Eyin ọmọ Yorùbá te fẹran Oge ṣise ati Aso wíwọ ilẹ Yorùbá , E sun mo bi, E gbe aga ki ẹ joko lati gbọ ohun ti mo ni fun yin.

Imura je ohun kan pataki ni ilẹ Yorùbá, Imura ni ohun ti ko lẹnu sugbon ti o maa n sọrọ, ti ọpọlọpọ ba gbọ Imura, Aṣọ wíwọ ni yoo wa si wọn lọkan sugbon imura ju aṣọ wíwọ lọ. Imura ko ohun ti o pọ sinu ni ilẹ Yorùbá, gẹgẹ bi Aṣọ wíwọ, Ileke lilo si ara ati irun ṣiṣe.
Awọn Yorùbá ni orisirisi Aṣọ ti a fin da wọn mọ yatọ si awọn ẹya miiran, wọn si fẹran lati maa se iyanran pẹlu Imura paapaa julọ nibi ayeye ati igbeyawo, Awon Yorùbá maa n pataki bi ọmọ ọkunrin tabi ọmọ obinrin ba se mura nitori won gbagbọ pe Imura a maa sọ iru eniyan ti ọkunrin naa tabi obinrin je ati irufẹ ile ti o ti jade. Wọn tun gbagbọ pe imura a maa royin ipo ti eniyan wa tabi dimu lawujọ.
Awọn Yorùbá ni aṣọ orisirisi ti wọn maa n wọ lọ si ayeye ọtọọtọ. Fun apẹẹrẹ ti won baa n se ifọbaje tabi ifinijoye, A o maa da ọba tabi awọn ti wọn fe je oye mọ pelu aṣọ ti o gbayi, ileke ati bata pelu irukere funfun lọwọ wọn.
Awọn ọkunrin Yoruba a maa wọ Buba, Esiki, Agbada, Gbariye pẹlu awọn awọtele ati sokoto orisirisi gẹgẹ bi Kembe, Sooro, Gbaanu pelu awọn fila bi Abeti Aja, Gọbi ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Awọn Obinrin Yorùbá a maa wọ Iro ati Buba, Gele, ati Iborun, wọn a si tun maa wọ ileke bi Iyun, Akun, Lagidigba boya si ọrun, ẹse tabi idi pẹlu orisirisi irundidalara bi kolẹse, Ipakọ-Elede, Suku, Kojusọkọ, Alagogo, Konkoso ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Ki obinrin wọ aṣọ lati bọ ihoho ara won ati ki ọkunrin maa se itoju ara pẹlu awọn imura to rẹwa je nkan pataki ni ilẹ Yorùbá, ọwọ ati ẹse nikan ni wọn ni ki obinrin ṣi silẹ ati ori wọn nigba miran. Wọn a maa fun obinrin ni ọwo to po ati itoju. Paapaa julọ awọn omidan, Ti awọn agbalagba obinrin yio maa se amojuto wọn nipa imura.
Nibi yi ni wun o maa danu duro si.
IBEERE! IBEERE!! IBEERE!!!
Talo mo o??
"Kini Itumo oro yi "
Òjò ti ńpa igún bọ̀, ọjọ́ ti pẹ́.
TRANSLATION
Am here again today2 with my culture shout outs,
Dressing is one of those7 things very important in the Yoruba land, Dressing is that thing that doesn't have mouth but speaks a lot, when2 a lot of people hear DRESSING, what comes to their mind is WEARING CLOTHES but 2dressing is more than Wearing Clothes, DRESSING encompasses a lot of things in the Yoruba land like Wearing Clothes, Use of Beads and Hair making.
Yoruba has different clothes8 that differentiate them from other tribes and their dressing is their Pride most especially when it comes to Occasions and Wedding Ceremonies. Yoruba gives6 lots of importance to how a Yoruba Man/Woman is dressed because they5 believe their dressing tells a lot about them and their various homes3. They also believe peoples dressing depicts their social status and personality in the society5.
The Yorubas have different dressing for different occasions, For Example1, when they are having coronation ceremony, We can easily recognize the king or the chiefs with2 their outstanding dresses, Crown, Beads and white Anthers in their hands.
Yoruba men usually wear3 Buba, Esiki, Agbada, Gbariye with different shorts and trousers like Sooro, Gbaanu with caps like Abeti Aja, Gobi and so on. While Yoruba women wear Iro and Buba, Gele and Iborun, They also wear beads 4like Iyun(Coral), Akun, Lagidigba whether6 on their necks, legs or waist with different lovely hair styles like kolese, Ipako-Elede, Suku, Kojusoko, Alagogo, Konkoso6.
Yoruba women and ladies covering their nakedness and men taking good care of themselves by dressing neatly is very important to the Yorubas. Females are only allowed to expose their hands, legs and sometimes their hair because they give more respect and care to women in the8 Yoruba land. Most especially the single ladies of which Elderly women are to look after them as regard their dressing.
This is where i will be stopping for this week.
Question!Question!! Question!!!
What does it mean when we say:
“Cut from the same cloth.”

LAUGH IT OUT ZONE
![]()
.
3REASURE HUNT
Is Time to Hunt For 3reasure

HINTS
- MTN Recharge Card
- Just Within The English Translation.
- From The First Line To The Last Line.
SPECIAL APPRECIATION
I specially appreciate everyone who took their time to join me on this show.
Most especially those that motivated me to bring this PROGRAM Alive with their full support.
,
,
,
,
,
,
,
,
,
, and
members.
STAY COOL TILL I COME NEXT WEEK.
LOVE YOU ALL »»»»»»KISSES»»»»»>MUAH!!!
DON'T FORGET TO»»»»»»»»»»»»»»
